Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  July 2017

July 10-​16

Ìsíkíẹ́lì 15-17

July 10-​16
 • Orin 11 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Ṣé O Máa Ń Mú Ìlérí Rẹ Ṣẹ?”: (10 min.)

  • Isk 17:​1-4​—Bábílónì fi Sedekáyà rọ́pò Ọba Jèhóákínì (w07 7/1 12 ¶6)

  • Isk 17:​7, 15​—Sedekáyà dalẹ̀, ó sì wá ìrànlọ́wọ́ lọ sí ilẹ̀ Íjíbítì (w07 7/1 12 ¶6)

  • Isk 17:​18, 19​—Jèhófà fẹ́ kí Sedekáyà mú àdéhùn rẹ̀ ṣẹ (w12 10/15 30 ¶11; w88 9/15 17 ¶8)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Isk 16:60​—Kí ni “májẹ̀mú tí ó wà fún àkókò tí ó lọ kánrin,” àwọn wo sì ni ọ̀rọ̀ náà kàn? (w88 9/15 17 ¶7)

  • Isk 17:​22, 23​—Ta ni “èyí tí ó jẹ́ ọ̀jẹ̀lẹ́” tí Jèhófà sọ pé òun yóò gbìn? (w07 7/1 12 ¶6)

  • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

  • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Isk 16:​28-42

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

 • Orin 36

 • Mú Ẹ̀jẹ́ Ìgbéyàwó Rẹ Ṣẹ Kódà Bí Ìgbéyàwó Rẹ Kò Bá Rí Bó O Ṣe Rò: (10 min.) Alàgbà ni kó sọ àsọyé yìí, a gbé e ka Jí! May 2014 ojú ìwé 12-13.

 • Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà​Jẹ́ Olóòótọ́: (5 min.) Jẹ́ káwọn ará wo fídíò yìí Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà​—Jẹ́ Olóòótọ́. Lẹ́yìn náà, pe àwọn ọmọdé tó o ti yàn tẹ́lẹ̀ wá sórí pèpéle, kó o sì bi wọ́n láwọn ìbéèrè tó dá lórí fídíò náà.

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 15 ¶1-8

 • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

 • Orin 137 àti Àdúrà