Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

July 4 sí 10

SÁÀMÙ 60-68

July 4 sí 10
 • Orin 104 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Ẹ Yin Jèhófà, Olùgbọ́ Àdúrà”: (10 min.)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Sm 63:3—Kí nìdí tí inú rere onífẹ̀ẹ́ Jèhófà fi sàn ju ìyè? (w06 6/1 ojú ìwé 11 ìpínrọ̀ 7)

  • Sm 68:18—Àwọn wo ni “àwọn ẹ̀bùn tí ó jẹ́ ènìyàn”? (w06 6/1 ojú ìwé 10 ìpínrọ̀ 5)

  • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

  • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sm 63:1–64:10

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Múra Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Oṣù Yìí Sílẹ̀: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn fídíò ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀, kó o sì jíròrò àwọn kókó pàtàkì látinú àwọn fídíò náà. Gba àwọn ará níyànjú pé kí wọ́n kọ àwọn ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ wọn sílẹ̀.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

 • Orin 81

 • Jẹ́ Kí Ohun Díẹ̀ Tẹ́ Ọ Lọ́rùn Kó O Lè Túbọ̀ Máa Yin Ọlọ́run”: (15 min.) Ẹ kọ́kọ́ jíròrò àpilẹ̀kọ náà. Lẹ́yìn náà, jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò tá a pe àkọlé rẹ̀ ní A Jẹ́ Kóhun Díẹ̀ Tẹ́ Wa Lọ́rùn, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀ ní ṣókí. Fídíò yìí wà lórí ètò Tẹlifíṣọ̀n JW (Lọ sí WO FÍDÍÒ LÓRÍṢIRÍṢI > ÌDÍLÉ.) Gba àwọn ará níyànjú pé kí wọ́n wo àwọn ọ̀nà tí wọ́n lè gbà jẹ́ kí ohun díẹ̀ tẹ́ wọn lọ́rùn kí wọ́n lè túbọ̀ máa sin Jèhófà.

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) ia orí 19 ìpínrọ̀ 1 sí 16

 • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

 • Orin 88 àti Àdúrà