Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  July 2016

July 18 sí 24

SÁÀMÙ 74-78

July 18 sí 24
 • Orin 110 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Máa Rántí Àwọn Iṣẹ́ Jèhófà”: (10 min.)

  • Sm 74:16; 77:6, 11, 12—Máa ṣàṣàrò lórí àwọn iṣẹ́ Jèhófà (w15 8/15 ojú ìwé 10 ìpínrọ̀ 3 àti 4; w04 3/1 ojú ìwé 19 àti 20; w03 7/1 ojú ìwé 10 ìpínrọ̀ 6 àti 7)

  • Sm 75:4-7—Lára àwọn iṣẹ́ Jèhófà ni bó ṣe yan àwọn ọkùnrin onírẹ̀lẹ̀ láti máa bójú tó ìjọ rẹ̀ (w06 7/15 ojú ìwé 11 ìpínrọ̀ 2; it-1 ojú ìwé 1160 ìpínrọ̀ 7)

  • Sm 78:11-17—Máa rántí bí Jèhófà ṣe gbèjà àwọn èèyàn rẹ̀ nígbà àtijọ́ (w04 4/1 ojú ìwé 21 àti 22)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Sm 78:2—Báwo ni Mèsáyà ṣe mú àsọtẹ́lẹ̀ tó wà nínú ẹsẹ Ìwé Mímọ́ yìí ṣẹ? (w11 8/15 ojú ìwé 11 ìpínrọ̀ 14)

  • Sm 78:40, 41—Kí ni àwọn ẹsẹ Bíbélì yìí jẹ́ ká mọ̀ nípa bí ìwà àti ìṣe wa ṣe máa ń rí lára Jèhófà? (w12 11/1 ojú ìwé 14 ìpínrọ̀ 5; w11 7/1 ojú ìwé 10)

  • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

  • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sm 78:1-21

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

 • Orin 15

 • Ohun tó ń fẹ́ àbójútó nínú ìjọ: (10 min.)

 • “Jèhófà . . . Ni Ó Dá Ohun Gbogbo”: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò yìí tó wà lórí ìkànnì jw.org/yo (Lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀWỌN ỌMỌDÉ.) Lẹ́yìn náà, pe àwọn ọmọdé bíi mélòó kan wá sórí pèpéle, kó o sì bi wọ́n ní ìbéèrè nípa fídíò náà.

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) ia orí 20 ìpínrọ̀ 1 sí 13

 • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

 • Orin 73 àti Àdúrà