Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁTÍÙ 6-7

Máa Wá Ìjọba Náà Lákọ̀ọ́kọ́

Máa Wá Ìjọba Náà Lákọ̀ọ́kọ́

Nínú àdúrà àwòfiṣàpẹẹrẹ, Jésù jẹ́ kó ṣe kedere pé àwọn ọ̀rọ̀ tó jẹ mọ́ àwọn ohun tí Jèhófà fẹ́ ṣe àti Ìjọba rẹ̀ ló yẹ ká fi sípò àkọ́kọ́.

6:9-13

 • Orúkọ Ọlọ́run

  Ìjọba Ọlọ́run

  Ohun tí Ọlọ́run fẹ́

 • Oúnjẹ òòjọ́

  Ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀

  Bá a ṣe máa bọ́ lọ́wọ́ ìdẹwò

Àwọn ohun tó jẹ mọ́ Ìjọba náà tí mo lè gbàdúrà fún:

 • Kí iṣẹ́ ìwàásù máa tẹ̀ síwájú

 • Kí ẹ̀mí mímọ́ Ọlọ́run ran àwọn tí wọ́n ń ṣe inúnibíni sí lọ́wọ́

 • Kí Ọlọ́run bù kún iṣẹ́ tí àwọn tó ń kọ́ ilé fún ètò Ọlọ́run ń ṣe lọ́wọ́ níbì kan tàbí níbi tí wọ́n ti ń ṣe àkànṣe iṣẹ́ ìwàásù

 • Kí Ọlọ́run fún àwọn tó ń mú ipò iwájú ní ọgbọ́n àti agbára láti bójú tó iṣẹ́ wọn

 • Àwọn ohun míì