●○○ NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́

Ìbéèrè: Ṣé o rò pé Bíbélì ṣì wúlò fún wa lóde òní?

Bíbélì: 2Ti 3:16

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí ni Bíbélì dá lé?

○●○ ÌPADÀBẸ̀WÒ ÀKỌ́KỌ́

Ìbéèrè: Kí ni Bíbélì dá lé?

Bíbélì: Mt 6:10

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí ni Ìjọba Ọlọ́run máa ṣe?

○○● ÌPADÀBẸ̀WÒ KEJÌ

Ìbéèrè: Kí ni Ìjọba Ọlọ́run máa ṣe?

Bíbélì: Da 2:44

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo ni ayé ṣe máa wá rí?