Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  January 2017

January 9-​15

AÍSÁYÀ 29-33

January 9-​15
 • Orin 123 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Ọba Kan Yóò Jẹ fún Òdodo”: (10 min.)

  • Ais 32:1​—Jésù Kristi ni Ọba tó máa jẹ fún òdodo (w14 2/15 6 ¶13)

  • Ais 32:2​—Jésù tó ti di ọba pèsè àwọn ọmọ aládé tó máa bójú tó agbo rẹ̀ (ip-1 332-334 ¶7-8)

  • Ais 32:​3, 4​—Àwọn èèyàn Jèhófà ń rí ìtọ́ni àti ìdálẹ́kọ̀ọ́ gbà tó jẹ́ kí wọ́n lè jẹ́ olódodo (ip-1 334-335 ¶10-11)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Ais 30:21​—Àwọn ọ̀nà wo ni Jèhófà ń gbà bá àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ sọ̀rọ̀? (w14 8/15 21 ¶2)

  • Ais 33:22​—Ìgbà wo ni Jèhófà di Onídàájọ́, Ẹni tí ń fúnni ní ìlànà àgbékalẹ̀, àti Ọba fún orílẹ̀-èdè Ísírẹ́lì, báwo ló sì ṣe dì í? (w14 10/15 14 ¶4)

  • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

  • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ais 30:22-33

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Kókó iwájú ìwé ìròyìn wp17.1​—Fún onílé tínú ń bí lésì.

 • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Kókó iwájú ìwé ìròyìn wp17.1​—Ka ẹsẹ Ìwé Mímọ́ látorí fóònù tàbí tablet.

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv 31-32 ¶12-13​—Ṣe àṣefihàn béèyàn ṣe lè dé ọkàn akẹ́kọ̀ọ́.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI