WÒÓ
Ọ̀rọ̀
Àwòrán

Ní nǹkan bí igba [200] ọdún kí ìlú Bábílónì tó pa run, Jèhófà ti gbẹnu Aísáyà sọ kúlẹ̀kúlẹ̀ ohun tó máa ṣẹlẹ̀.

44:27–45:2

  • Kírúsì ló máa ṣẹ́gun Bábílónì

  • Àwọn ilẹ̀kùn aláwẹ́ méjì rẹ̀ máa wà ní ṣíṣí sílẹ̀

  • Odò Yúfírétì wà lára ohun tí wọ́n fi ń dáàbò bo ìlú náà, àmọ́ ó máa “gbẹ táútáú”