Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

January 30–​February 5

Aísáyà 43-46

January 30–​February 5
 • Orin 33 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Jèhófà Ni Ọlọ́run Tó Ń Sọ Àsọtẹ́lẹ̀ Tí Kìí Yẹ̀”: (10 min.)

  • Ais 44:26-28​—Jèhófà sọ tẹ́lẹ̀ pé wọ́n máa tún Jerúsálẹ́mù àti tẹ́ńpìlì rẹ̀ kọ́, ó sì tún sọ pé Kírúsì lẹni tó máa ṣẹ́gun ìlú Bábílónì (ip-2 71-72 ¶22-23)

  • Ais 45:1, 2​—Jèhófà sọ kúlẹ̀kúlẹ̀ nípa bí wọ́n ṣe máa ṣẹ́gun ìlú Bábílónì (ip-2 77-78 ¶4-6)

  • Ais 45:3-6​—Jèhófà sọ ìdí tó fi jẹ́ pé Kírúsì ni òun lò láti ṣẹ́gun ìlú Bábílónì (ip-2 79-80 ¶8-10)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Ais 43:10-12​—Ọ̀nà wo làwọn ọmọ Ísírẹ́lì gbà jẹ́ orílẹ̀-èdè tó jẹ́ ẹlẹ́rìí fún Jèhófà? (w14 11/⁠⁠15 21-22 ¶14-16)

  • Ais 43:25​—Kí nìdí tí Jèhófà fi ń mú àwọn ìrélànàkọjá wa kúrò? (ip-2 60 ¶24)

  • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

  • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ais 46:​1-13

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) fg​—Jẹ́rìí lọ́nà àìjẹ́ bí àṣà fún ẹni tẹ́ ẹ jọ ń ṣiṣẹ́ tàbí ọmọléèwé rẹ.

 • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) fg​—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) jl ẹ̀kọ́ 4

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI