Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

January 23-​29

Aísáyà 38-42

January 23-​29
 • Orin 78 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Jèhófà Ń Fi Agbára fún Ẹni Tó Ti Rẹ̀”: (10 min.)

  • Ais 40:25, 26​—Jèhófà ni Orísun gbogbo agbára (ip-1 409-410 ¶23-25)

  • Ais 40:27, 28​—Jèhófà ń rí gbogbo ohun tí à ń fara dà àti ìyà tó ń jẹ wá (ip-1 413 ¶27)

  • Ais 40:29-31​—Jèhófà máa ń fún àwọn tó gbẹ́kẹ̀ lé e lágbára (ip-1 413-415 ¶29-31)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Ais 38:17​—Ọ̀nà wo ni Jèhófà ń gbà ju àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa sí ẹ̀yìn rẹ̀? (w03 7/1 18 ¶17)

  • Ais 42:3​—Báwo ni àsọtẹ́lẹ̀ yìí ṣe ṣẹ sí Jésù lára? (w15 2/15 8 ¶13)

  • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

  • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ais 40:​6-17

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) fg​—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.

 • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) fg​—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv 38-39 ¶6-7​—Ṣe àṣefihàn béèyàn ṣe lè dé ọkàn akẹ́kọ̀ọ́.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI