Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  January 2017

January 2-​8

Aísáyà 24-28

January 2-​8
 • Orin 12 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Jèhófà Máa Ń Bójú Tó Àwọn Èèyàn Rẹ̀”: (10 min.)

  • Ais 25:4, 5​—Jèhófà jẹ́ ibi ààbò nípa tẹ̀mí fún àwọn tó fẹ́ jọ́sìn rẹ̀ (ip-1 272 ¶5)

  • Ais 25:6​—Jèhófà ti mú ìlérí rẹ̀ ṣẹ pé òun máa pèsè oúnjẹ tẹ̀mí fún wa lọ́pọ̀ yanturu (w16.05 24 ¶4; ip-1 273 ¶6-7)

  • Ais 25:7, 8​—Ọlọ́run máa tó mú ẹ̀ṣẹ̀ àti ikú kúrò títí láé (w14 9/15 26 ¶15; ip-1 273-274 ¶8-9)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Ais 26:15​—Báwo la ṣe lè ṣèrànwọ́ bí Jèhófà ṣe ń “sún gbogbo ojú ààlà ilẹ̀ náà síwájú”? (w15 7/15 11 ¶18)

  • Ais 26:20​—Kí ló ṣeé ṣe kí àsọtẹ́lẹ̀ nípa ‘yàrá inú lọ́hùn-ún’ tọ́ka sí? (w13 3/15 23 ¶15-16)

  • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

  • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ais 28:1-13

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI