Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Wọ́n ń wàásù ìhìn rere ní Gánà

ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI January 2017

Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò

Àwọn ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ tá a lè lò láti fi ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́ lọni àti kíkọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ òtítọ́ nípa àwọn àmì ọjọ́ ikẹ̀yin. Lo àbá yìí láti fi kọ ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ rẹ.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Jèhófà Máa Ń Bójú Tó Àwọn Èèyàn Rẹ̀

Bí ọ̀làwọ́ èèyàn ti máa ń ṣe tó bá gbàlejò, bẹ́ẹ̀ ni Jèhófà ṣe ń pèsè oúnjẹ tẹ̀mí fún wa lọ́pọ̀ yanturu.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

“Ọba Kan Yóò Jẹ fún Òdodo”

Jésù tó jẹ́ Ọba wa fún wa ní àwọn alàgbà láti máa bójú tó agbo Ọlọ́run. Wọ́n ń ran agbo Ọlọ́run lọ́wọ́ láti rí ìtura àti ìtọ́sọ́nà.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ọlọ́run San Hesekáyà Lẹ́san Torí Pé Ó Nígbàgbọ́

Àwọn ará Ásíríà fẹ́ mú káwọn Júù juwọ́ sílẹ̀ láìjà, àmọ́ Jèhófà rán ańgẹ́lì rẹ̀ láti gba Jerúsálẹ́mù sílẹ̀.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

“Jìófà . . . Ìwọ Ni Mo Gbẹ́kẹ̀ Lé”

Ó ṣe pàtakì ká gbọ́kàn lé Jèhófà nígbà tí nǹkan dáa àti nígbà tó nira. Báwo ni Hesekáyà ṣe fi hàn pé òun gbẹ́kẹ̀ lé Ọlọ́run?

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Jèhófà Ń Fi Agbára fún Ẹni Tó Ti Rẹ̀

Bí ẹyẹ idì ṣe ń fò lókè ṣàpẹẹrẹ bí a ṣe ń bá ìjọsìn wa lọ pẹ̀lú agbára tí Jèhófà ń fún wa.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Máa Rántí Gbàdúrà Fáwọn Kristẹni Tí Wọ́n Ń Ṣe Inúnibíni Sí

Báwo la ṣe lè gbàdúrà ká lè ran àwọn Kristẹni tí wọ́n ń ṣe inúnibíni sí lọ́wọ́?

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Jèhófà Ni Ọlọ́run Tó Ń Sọ Àsọtẹ́lẹ̀ Tí Kìí Yẹ̀

Ní nǹkan bí igba [200] ọdún kí ìlú Bábílónì tó pa run, Jèhófà ti gbẹnu Aísáyà sọ kúlẹ̀kúlẹ̀ ohun tó máa ṣẹlẹ̀.