Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  January 2016

January 25 sí 31

Ẹ́SÍRÀ 6-10

January 25 sí 31
 • Orin 10 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Àwọn Tó Ń Fi Tinútinú Yọ̀ǹda Ara Wọn Ni Jèhófà Fẹ́”: (10 min.)

  • Ẹsr 7:10—Ẹ́sírà múra ọkàn rẹ̀ sílẹ̀

  • Ẹsr 7:12-28—Ẹ́sírà ṣètò láti pa dà sí Jerúsálẹ́mù

  • Ẹsr 8:21-23—Ẹ́sírà gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà pé yóò dáàbò bo àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Ẹsr 9:1, 2—Báwo ni ọ̀rọ̀ fífẹ́ lára “àwọn èèyàn ilẹ̀ náà” ṣe burú tó? (w06 1/15 ojú ìwé 20 ìpínrọ̀ 1)

  • Ẹsr 10:3—Kí nìdí tí wọ́n fi lé àwọn aya àwọn ọmọ Ísírẹ́lì lọ tọmọtọmọ? (w06 1/15 ojú ìwé 20 ìpínrọ̀ 2)

  • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

  • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

 • Bíbélì Kíkà: Ẹsr 7:18-28 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Fi ìwé Ìròyìn Ayọ̀ lọ ẹnì kan, ẹ jọ jíròrò ẹ̀kọ́ 8, ìbéèrè 1, ìpínrọ̀ 1. Sọ ohun tí wàá bá ẹni náà jíròrò nígbà tó o bá pa dà wá.

 • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ṣe àṣefihàn bí a ṣe lè ṣe ìpadàbẹ̀wò sọ́dọ̀ ẹnì kan tó gba ìwé Ìròyìn Ayọ̀. Ẹ jọ jíròrò ẹ̀kọ́ 8, ìbéèrè 1, ìpínrọ̀ 2. Sọ ohun tí wàá bá ẹni náà jíròrò nígbà tó o bá tún pa dà wá.

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ṣe àṣefihàn bí a ṣe ń ṣe ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì, fi ẹ̀kọ́ 8, ìbéèrè 2 nínú ìwé Ìròyìn Ayọ̀ ṣe é.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI