Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  February 2017

 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | AÍSÁYÀ 47-51

Jèhófà Máa Bù Kún Wa Tá A Bá Ṣègbọ́ràn Sí I

Jèhófà Máa Bù Kún Wa Tá A Bá Ṣègbọ́ràn Sí I

48:17

  • Jèhófà nífẹ̀ẹ́ wa, torí náà ó ń mú ká máa tọ ‘ọ̀nà tí ó yẹ kí a máa rìn,’ ká báa lè gbádùn ìgbésí ayé wa. Tá a bá ṣègbọràn sí i, àwa la máa jàǹfààní ẹ̀

“Àlàáfíà . . . dà bí odò”

48:18

  • Jèhófà ṣèlérí pé òun máa fún wa ní àlááfíà lọ́pọ̀ yanturu, tí kò sì ní lópin bí odò

“Òdodo . . . bí ìgbì òkun”

  • Ìwa òdodo wa yóò pọ̀ lọ súà, kò sì ní lóǹkà bí ìgbì òkun