Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

February 27–March 5

Aísáyà 63-66

February 27–March 5
 • Orin 19 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Ọ̀run Tuntun àti Ayé Tuntun Máa Mú Ká Láyọ̀ Tó Kọ Yọyọ”: (10 min.)

  • Ais 65:17—“Àwọn ohun àtijọ́ ni a kì yóò sì mú wá sí ìrántí” (ip-2 383 ¶23)

  • Ais 65:18, 19—A máa láyọ̀ tó kọ yọyọ (ip-2 384 ¶25)

  • Ais 65:21-23—A máa ní ìtẹ́lọ́rùn, ọkàn wa sì máa balẹ̀ (w12 9/15 9 ¶4-5)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Ais 63:5—Báwo ni ìhónú Ọlọ́run ṣe ń tì í lẹ́yìn? (w07 1/15 11 ¶6)

  • Ais 64:8—Báwo ni Jèhófà ṣe ń lo àṣẹ tó ní gẹ́gẹ́ bí amọ̀kòkò wa? (w13 6/15 25 ¶3-)

  • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

  • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ais 63:1-10

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ef 5:33—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni.

 • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 1Ti 5:8; Tit 2:4, 5—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni.

 • Àsọyé: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ais 66:23; w06 11/1 30-31 ¶14-17—Àkòrí: Pípàdé Pọ̀—Ohun Kan Tí Kò Ní Yí Padà Nínú Ìjọsìn Wa

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI