Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

February 20-26

Aísáyà 58-62

February 20-26
 • Orin 142 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Pòkìkí Ọdún Ìtẹ́wọ́gbà Níhà Ọ̀dọ̀ Jèhófà”: (10 min.)

  • Ais 61:1, 2—Ọlọ́run fòróró yan Jésù “láti pòkìkí ọdún ìtẹ́wọ́gbà níhà ọ̀dọ̀ Jèhófà” (ip-2 322 ¶4)

  • Ais 61:3, 4—Jèhófà pèsè “igi ńlá òdodo” láti ṣe iṣẹ́ rẹ̀ (ip-2 326-327 ¶13-15)

  • Ais 61:5, 6—“Àwọn ọmọ ilẹ̀ òkèèrè” ń fọwọ́ sowó pọ̀ pẹ̀lú àwọn “àlùfáà Jèhófà” lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù tó tíì gbòòrò jù lọ nínú ìtàn aráyé (w12 12/15 25 ¶5-6)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Ais 60:17—Kí ni díẹ̀ lára àwọn ọ̀nà tí Jèhófà ti gbà mú ìlérí yìí ṣẹ láwọn ọjọ́ ìkẹyìn? (w15 7/15 9-10 ¶14-17)

  • Ais 61:8, 9—Kí ni “májẹ̀mú tí ó wà fún àkókò tí ó lọ kánrin,” àwọn wo sì ni “àwọn ọmọ”? (w07 1/15 11 ¶5)

  • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

  • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ais 62:1-12

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI