Oṣù Tíṣírì, ọdún 455 Ṣ.S.K.

8:1-18

  1. Ó ṣeé ṣe kó jẹ́ pé àkókò yìí ni Nehemáyà sọ fáwọn èèyàn náà pé kí wọ́n kóra jọ láti jọ́sìn Ọlọ́run

  2. Àwọn èèyàn náà yọ ayọ̀ ńláǹlà

  3. Àwọn olórí ìdílé kóra jọ láti sọ̀rọ̀ lórí bí wọ́n á ṣe máa pa Òfin Ọlọ́run mọ́ délẹ̀délẹ̀

  4. Àwọn èèyàn náà kóra jọ láti ṣe Àjọyọ̀ Àtíbàbà