Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

February 8 sí 14

NEHEMÁYÀ 5-8

February 8 sí 14
 • Orin 123 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Alábòójútó Tó Ṣàrà Ọ̀tọ̀ Ni Nehemáyà”: (10 min.)

  • Ne 5:1-7—Nehemáyà tẹ́tí sí àwọn èèyàn náà, ó sì gbé ìgbésẹ̀ (w06 2/1 ojú ìwé 9 ìpínrọ̀ 2)

  • Ne 5:14-19—Nehemáyà jẹ́ onírẹ̀lẹ̀, aláìmọ̀-tara-ẹni-nìkan àti olóye (w06 2/1 ojú ìwé 10 ìpínrọ̀ 4)

  • Ne 8:8-12—Nehemáyà kópa nínú kíkọ́ àwọn èèyàn náà ní Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run (w06 2/1 ojú ìwé 11 ìpínrọ̀ 4)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Ne 6:5—Kí nìdí tí Sáńbálátì ṣe fi “lẹ́tà tí a kò lẹ̀” ránṣẹ́ sí Nehemáyà? (w06 2/1 ojú ìwé 9 ìpínrọ̀ 3)

  • Ne 6:10-13—Kí nìdí tí Nehemáyà kò fi gba ìmọ̀ràn Ṣemáyà? (w07 7/1 ojú ìwé 30 ìpínrọ̀ 15)

  • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

  • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

 • Bíbélì Kíkà: Ne 6:14–7:7a (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Fi àpilẹ̀kọ tó dá lórí kókó iwájú ìwé ìròyìn Jí! ti lọ́ọ́lọ́ọ́ lọni. Sọ ohun tí wàá bá ẹni náà jíròrò nígbà tó o bá pa dà wá..

 • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ṣe àṣefihàn bí a ṣe lè ṣe ìpadàbẹ̀wò ẹni tó nífẹ̀ẹ́ sí àpilẹ̀kọ tó dá lórí kókó iwájú ìwé ìròyìn Jí! ti lọ́ọ́lọ́ọ́ tí wọ́n fi lọ̀ ọ́. Sọ ohun tí wàá bá ẹni náà jíròrò nígbà tó o bá tún pa dà wá.

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ṣe àṣefihàn bí a ṣe máa ń ṣe ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì. (bh ojú ìwé 28 sí 29 ìpínrọ̀ 4 àti 5)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI