Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

December 4-​10

SEFANÁYÀ 1–HÁGÁÌ 2

December 4-​10
 • Orin 151 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Ẹ Wá Jèhófà Kí Ọjọ́ Ìbínú Rẹ̀ Tó Dé”: (10 min.)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Sef 1:8​—Ìkìlọ̀ wo ló wà nínú ẹsẹ Bíbélì yìí? (w07 11/15 11¶3)

  • Hag 2:9​—Àwọn ọ̀nà wo ni ògo tẹ́ńpìlì Serubábélì gbà ju ti tẹ́ńpìlì Sólómọ́nì lọ? (w07 12/1 9¶3)

  • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

  • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Hag 2:1-14

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Múra Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Oṣù Yìí Sílẹ̀: (15 min.) Ìjíròrò tó dá lórí “Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò.” Jẹ́ kí àwọn ará wo ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn fídíò ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀, kẹ́ ẹ sì jíròrò àwọn kókó pàtàkì látinú àwọn fídíò náà. Gba àwọn ará níyànjú pé kí wọ́n fún ọ̀pọ̀ èèyàn ní ìwé ìròyìn Jí! No.6 2017. Àmọ́, torí pé a fẹ́ bá àwọn èèyàn sọ̀rọ̀ ní tààràtà, a ò ní fi sí ẹnu ọ̀nà àwọn tí kò bá sí nílé.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

 • Orin 30

 • Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (5 min.)

 • Èdè Mímọ́ Tó Ń Mú Kí Àlàáfíà àti Ìṣọ̀kan Túbọ̀ Máa Gbilẹ̀ (Sef 3:9): (10 min.) Ìjíròrò tó dá lórí Ilé Ìṣọ́ August 15, 2012, ojú ìwé 12, ìpínrọ̀ 4. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà, Ọ̀tá Ni Wọ́n Tẹ́lẹ̀, Àmọ́ Ọ̀rẹ́ Ni Wọ́n Báyìí.

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 22 ¶8-16

 • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3min.)

 • Orin 136 àti Àdúrà