Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁLÁKÌ 1-4

Ṣé Ìgbéyàwó Rẹ Ń Múnú Jèhófà Dùn?

Ṣé Ìgbéyàwó Rẹ Ń Múnú Jèhófà Dùn?

2:13-16

  • Nígbà ayé Málákì, ìkọ̀sílẹ̀ wọ́pọ̀ láàárín àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, èyí sì máa ńjẹ́ lórí ẹ̀sùn tí kò lẹ́sẹ̀ nílẹ̀. Jèhófà kò tẹ́wọ́ gba ìjọsìn àwọn tó ńṣe àdàkàdekè sí ọkọ tàbí aya wọn

  • Jèhófà bù kún àwọn tó ńṣìkẹ́ ọkọ tàbí aya wọn

Lónìí, báwo ni àwọn tọkọtaya ṣe lè jẹ́ olóòótọ́ sí ara wọn nínú...

  • èrò wọn?

  • ohun tí wọ́n ńwò?

  • ọ̀rọ̀ wọn?