• Orin 36 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Ṣé Ìgbéyàwó Rẹ Ń Múnú Jèhófà Dùn?”: (10 min.)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Mal 1:10​—Kí nìdí tó fi yẹ kó jẹ́ pé ìfẹ́ aláìmọtara-ẹni-nìkan tá a ní fún Ọlọ́run àti fún àwọn èèyàn ló ńmú ká jọ́sìn Ọlọ́run? (w07 12/15 27¶1)

  • Mal 3:1​—Báwo ni ẹsẹ Bíbélì yìí ṣe nímùúṣẹ ní ọgọ́rùn-ún ọdún kìíní àti lákòókò yìí? (w13 7/15 10-11 ¶5-6)

  • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

  • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀yìí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Mal 1:​1-10

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 1Kọ 15:26​—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni.

 • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ais 26:19; 2Kọ 1:​3,4​—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni. (Wo mwb16.08 8 ¶2.)

 • Àsọyé: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w07 12/15 28 ¶1​—Àkòrí: Báwo La Ṣe Lè Kó Gbogbo Ìdá Mẹ́wàá Wa Wá Sínú Ilé Ìtọ́jú Nǹkan Pa Mọ́ Lónìí?

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

 • Orin 87

 • Kí Ni Ìfẹ́ Tòótọ́?”: (15 min.) Ìbéèrè àti ìdáhùn.

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv orí 1 ¶10-18, àpótí tó wà lójú ìwé 13 [Kò pọn dandan kẹ́ ẹ jíròrò àpótí tàbí àfikún àlàyé]

 • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3min.)

 • Orin 114 àti Àdúrà