Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  December 2017

 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | SEKARÁYÀ 9-14

Dúró sí “Àfonífojì Àwọn Òkè Ńlá”

Dúró sí “Àfonífojì Àwọn Òkè Ńlá”

14:3-5

Jèhófà ṣe “afonífojì ńlá” kan lọ́dún 1914 nígbà tó gbé Ìjọba Mèsáyà kalẹ̀, Ìjọba yìí tó jẹ́ “òkè ńlá” wà lábẹ́ àkóso rẹ̀. Láti ọdún 1919, “àfonífojì àwọn òkè ńlá” náà ti di ibi ààbò fún àwọn ìránṣẹ́ Ọlọ́run

Báwo ni àwọn èèyàn ṣe ń “sá lọ sí àfonífojì” ààbò?

14:​12, 15

Àwọn tí kò bá dúró sí àfonífojì náà máa pa run nígbà Amágẹ́dọ́nì

Báwo ni mo ṣe lè dúró sí àfonífojì ààbò?