Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  December 2017

December 11-​17

SEKARÁYÀ 1-8

December 11-​17
 • Orin 146 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • ‘Di Aṣọ Ọkùnrin Tó Jẹ́ Júù Mú’: (10 min.)

  • [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Sekaráyà.]

  • Sek 8:​20-22​—Àwọn èèyàn láti inú gbogbo èdè àti orílẹ̀-èdè ńwá ojúure Jèhófà (w14 11/15 27 ¶14)

  • Sek 8:23​—Àwọn tó ní ìrètí láti wà lórí ilẹ̀ ayé ńfi tinútinú tọ àwọn ẹni àmì òróró lẹ́yìn, wọ́n sì ń ṣètìlẹ́yìn fún wọn (w16.01 21 ¶4; w09 2/15 27 ¶14)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Sek 5:​6-11​—Bí ìwà ibi tilẹ̀ kún inú ayé lónìí, kí ló yẹ kó jẹ́ ìpinnu wa? (w17.10 25 ¶18)

  • Sek 6:1​—Kí ni àwọn òkè ńlá bàbà méjì náà dúró fún? (w17.10 27-28 ¶7-8)

  • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

  • Àwọn ìṣura tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀yìí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sek 8:​14-23

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Kókó iwájú ìwé ìròyìn g17.6​—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.

 • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) g17.6Nígbà tó o kọ́kọ́ wàásù fún ẹni náà, o ti fún un ní ìwé ìròyìn yìí. Ṣe ìpadàbẹ̀wò, kó o sì jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) fg ẹ̀kọ́ 5 ¶1-2.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI