Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  December 2016

December 26–January 1

AÍSÁYÀ 17-23

December 26–January 1
 • Orin 123 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Àṣẹ Máa Ń Bọ́ Lọ́wọ́ Ẹni Tó Bá Ń Ṣi Agbára Lò”: (10 min.)

  • Ais 22:15, 16—Ṣẹ́bínà hùwà ìmọtara-ẹni-nìkan nígbà tó wà nípò àṣẹ (ip-1 ojú ìwé 238 ìpínrọ̀ 16 àti 17)

  • Ais 22:17-22—Jèhófà fi Élíákímù rọ́pò Ṣẹ́bínà (ip-1 ojú ìwé 238 àti 239 ìpínrọ̀ 17 àti 18)

  • Ais 22:23-25—Ẹ̀kọ́ pàtàkì ni ohun tó ṣẹlẹ̀ sí Ṣẹ́bínà kọ́ wa (w07 1/15 ojú ìwé 8 ìpínrọ̀ 6; ip-1 ojú ìwé 240 àti 241 ìpínrọ̀ 19 àti 20)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Ais 21:1—Àgbègbè wo ni Bíbélì pè ní “aginjù òkun,” kí sì nìdí? (w06 12/1 ojú ìwé 11 ìpínrọ̀ 3)

  • Ais 23:7, 18—Báwo ni àwọn ohun ìní tí Tírè jèrè ṣe jẹ́ “ohun mímọ́ lójú Jèhófà”? (ip-1 ojú ìwé 253 àti 254 ìpínrọ̀ 22 sí 24)

  • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

  • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ais 17:1-14

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bhLo fídíò Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? láti fi nasẹ̀ ìwé náà. (Àkíyèsí: Ẹ má ṣe wo fídíò yìí nígbà àṣefihàn náà.)

 • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh—Bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ẹnu ọ̀nà, kó o sì jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv ojú ìwé 150 àti 151 ìpínrọ̀ 10 àti 11—Fi béèyàn ṣe lè dé ọkàn akẹ́kọ̀ọ́ hàn.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI