Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

December 19-25

AÍSÁYÀ 11-16

December 19-25
 • Orin 143 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Ilẹ̀ Ayé Yóò Kún fún Ìmọ̀ Jèhófà”: (10 min.)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Ais 11:1, 10—Báwo ni Jésù Kristi ṣe lè jẹ́ “gbòǹgbò Jésè” síbẹ̀ kó tún jẹ́ ẹ̀ka igi kan tó yọ láti “ara kùkùté Jésè”? (w06 12/1 ojú ìwé 9 ìpínrọ̀ 6)

  • Ais 13:17—Ọ̀nà wo làwọn ará Mídíà kò fi ka fàdákà sí ohunkóhun tí Wọn kò sì ní inú dídùn sí wúrà? (w06 12/1 ojú ìwé 10 ìpínrọ̀ 10)

  • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

  • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ais 13:17–14:8

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Job 34:10—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni.

 • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Onw 8:9; 1Jo 5:19—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni.

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv ojú ìwé 54 ìpínrọ̀ 9—Fi béèyàn ṣe lè dé ọkàn akẹ́kọ̀ọ́ hàn.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI