Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  December 2016

December 12-18

AÍSÁYÀ 6-10

December 12-18
 • Orin 116 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Mèsáyà Tó Ní Ìmúṣẹ ”: (10 min.)

  • Ais 9:1, 2—Àsọtẹ́lẹ̀ ti wà nípa iṣẹ́ òjíṣẹ́ rẹ̀ ní Gálílì (w11 8/15 ojú ìwé 10 ìpínrọ̀ 13; ip-1 ojú ìwé 124 sí 126 ìpínrọ̀ 13 sí 17)

  • Ais 9:6—Ó máa ní ọ̀pọ̀ ojúṣe lónírúurú láti bójú tó (w14 2/15 ojú ìwé 12 ìpínrọ̀ 18; w07 5/15 ojú ìwé 6)

  • Ais 9:7—Ìṣàkóso rẹ̀ máa mú àlááfíà àti ìdájọ́ òdodo wá fún aráyé (ip-1 ojú ìwé 132 ìpínrọ̀ 28 àti 29)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Ais 7:3, 4—Kí nìdí tí Jèhófà fi dáàbò bo Áhásì Ọba tó jẹ́ ẹni burúkú? (w06 12/1 ojú ìwé 9 ìpínrọ̀ 4)

  • Ais 8:1-4—Báwo ni àsọtẹ́lẹ̀ yìí ṣe ní ìmúṣẹ? (it-1-E ojú ìwé 1219; ip-1 ojú ìwé 111 àti 112 ìpínrọ̀ 23 àti 24)

  • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

  • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ais 7:1-17

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Àwòrán iwájú ìwé ìròyìn g16.6 tó wà lójú ìwé 2

 • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Kókó iwájú ìwé ìròyìn g16.6

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv ojú ìwé 34 ìpínrọ̀ 18—Fi béèyàn ṣe lè dé ọkàn akẹ́kọ̀ọ́ hàn.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI