Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  August 2017

 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌSÍKÍẸ́LÌ 28-31

Jèhófà San Ìlú Abọ̀rìṣà Kan Lẹ́san

Jèhófà San Ìlú Abọ̀rìṣà Kan Lẹ́san

29:18-20

Bí Jèhófà bá lè san ìlú abọ̀rìṣà lẹ́san fún iṣẹ́ tó ṣe, ó dájú pé ó máa san àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ olóòótọ́ lẹ́san fún iṣẹ́ tí wọ́n ṣe!

OHUN TÍ BÁBÍLÓNÌ ṢE

Wọ́n sàga ti ìlú Tírè

OHUN TÍ MÀÁ ṢE

Irú ogun tẹ̀mí wo ni mò ń jà?

OHUN TÍ OJÚ ÀWỌN ARÁ BÁBÍLÓNÌ RÍ

  • Ọdún mẹ́tàlá ni wọ́n fi sàga ti ìlú Tírè, owó kékeré kọ́ nìyẹn sì ná wọn

  • Àwọn ọmọ ogun Bábílónì jìyà

  • Àwọn ará Bábílónì kò rí owó kankan gbà

ÀWỌN NǸKAN TÍ MO YÁÁFÌ

Àwọn nǹkan wo ni mo ti yááfì lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn mi sí Jèhófà?

BÍ JÈHÓFÀ ṢE SAN BÁBÍLÓNÌ LẸ́SAN

Jèhófà fi Íjíbítì lé wọn lọ́wọ́ gẹ́gẹ́ bí ohun ìfiṣèjẹ

BÍ JÈHÓFÀ ṢE SAN MÍ LẸ́SAN

Báwo ni Jèhófà ṣe san mí lẹ́san?