Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  August 2017

August 7-​13

Ìsíkíẹ́lì 28-31

August 7-​13
 • Orin 85 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Jèhófà San Ìlú Abọ̀rìṣà Kan Lẹ́san”: (10 min.)

  • Isk 29:18​—⁠Nebukadinésárì ọba Bábílónì kò gba èrè kankan fún bó ṣe ṣẹ́gun ìlú Tírè (it-2 1136 ¶4)

  • Isk 29:19​—⁠Ọba Nebukadinésárì gba Íjíbítì gẹ́gẹ́ bí ohun ìfiṣèjẹ dípò Tírè (it-1 698 ¶5)

  • Isk 29:20​—⁠Jèhófà san àwọn ará Bábílónì lẹ́san torí pé wọ́n ṣe ohun tó bá ìfẹ́ rẹ̀ mu (g86 11/⁠8 27 ¶4-5)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Isk 28:​12-19​—⁠Báwo ni ìwà tí àwọn alákòóso ìlú Tírè hù ṣe jọ irú ìwà tí Sátánì hù? (it-2 604 ¶4-5)

  • Isk 30:​13, 14​—⁠Báwo ni àsọtẹ́lẹ̀ yìí ṣe ní ìmúṣẹ? (w03 7/⁠1 32 ¶1-3)

  • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

  • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Isk 29:​1-12

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Múra Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Oṣù Yìí Sílẹ̀: (15 min.) Ìjíròrò tó dá lórí “Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò.” Jẹ́ kí àwọn ará wo ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn fídíò ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀, kẹ́ ẹ sì jíròrò àwọn kókó pàtàkì látinú àwọn fídíò náà. Gba àwọn ará níyànjú pé kí wọ́n mẹ́nu ba àwọn nǹkan tó ń ṣẹlẹ̀ lákòókò tá a wà yìí tí wọ́n bá ń gbé ọ̀rọ̀ wọn kalẹ̀, kí wọ́n sì lo fídíò náà Ṣé O Fẹ́ Gbọ́ Ìròyìn Ayọ̀? nígbà tí wọ́n bá ń fi ìwé Ìròyìn Ayọ̀ lọni.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI