Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  August 2017

 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌSÍKÍẸ́LÌ 39-41

Bí Ìran Tẹ́ńpìlì Tí Ìsíkíẹ́lì Rí Ṣe Kàn Ọ́

Bí Ìran Tẹ́ńpìlì Tí Ìsíkíẹ́lì Rí Ṣe Kàn Ọ́

40:​10, 14, 16

  • Àwọn ìyẹ̀wù tàbí yàrá ẹ̀ṣọ́ àti àwọn òpó gíga ń jẹ́ ká mọ̀ pé Jèhófà ní àwọn ìlànà tó ga fún ìjọsìn rẹ̀ mímọ́

  • Bi ara rẹ pé, ‘Àwọn nǹkan wo ni mo lè ṣe tó máa fi hàn pé mo fara mọ́ àwọn ìlànà Jèhófà?’