Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  August 2017

August 28–​September 3

Ìsíkíẹ́lì 39-41

August 28–​September 3
 • Orin 107 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Bí Ìran Tẹ́ńpìlì Tí Ìsíkíẹ́lì Rí Ṣe Kàn Ọ́”: (10 min.)

  • Isk 40:2​—⁠Ìjọsìn Jèhófà ga ju gbogbo ìjọsìn yòókù lọ (w99 3/⁠1 11 ¶16)

  • Isk 40:​3, 5​—⁠Ohun tí Jèhófà ní lọ́kàn nípa ìjọsìn mímọ́ máa ṣẹ (w07 8/⁠1 10 ¶2)

  • Isk 40:​10, 14, 16​—⁠Tá a bá fẹ́ kí Jèhófà tẹ́wọ́ gba ìjọsìn wa, a gbọ́dọ̀ máa fi àwọn ìlànà rẹ̀ mímọ́ sílò (w07 8/⁠1 11 ¶4)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Isk 39:7​—⁠Tí àwọn èèyàn bá ń dá Ọlọ́run lẹ́bi fún ìwà ìrẹ́jẹ tó kún inú ayé, báwo nìyẹn ṣe ń kó ẹ̀gàn bá orúkọ Ọlọ́run? (w12 9/⁠1 21 ¶2)

  • Isk 39:9​—⁠Lẹ́yìn ogun Amágẹ́dọ́nì, kí ló máa ṣẹlẹ̀ sí àwọn ohun ìjà tí àwọn orílẹ̀-èdè fi sílẹ̀? (w89 8/⁠15 14 ¶20)

  • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

  • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Isk 40:​32-47

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI