Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  August 2017

 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌSÍKÍẸ́LÌ 35-38

Gọ́ọ̀gù Ti Ilẹ̀ Mágọ́gù Máa Tó Pa Run

Gọ́ọ̀gù Ti Ilẹ̀ Mágọ́gù Máa Tó Pa Run

Bíbélì ṣàlàyé àwọn nǹkan tó máa ṣẹlẹ̀ kí Gọ́ọ̀gù ti ilẹ̀ Mágọ́gù tó pa run àti lẹ́yìn tó bá pa run.

 • Iṣi 17:16-18

  Ìparun kí ló máa bẹ̀rẹ̀ ìpọ́njú ńlá?

 • Isk 38:2, 11, 15

  Ta ló máa gbéjà ko àwa èèyàn Jèhófà?

 • Iṣi 16:16

  Ogun wo ni Jèhófà máa fi pa Gọ́ọ̀gù ti ilẹ̀ Mágọ́gù run?

 • Iṣi 20:4

  Ọdún mélòó ni Kristi fi máa ṣàkóso?

Báwo ni mo ṣe lè múra sílẹ̀ nípa tẹ̀mí de ìgbà tí Gọ́ọ̀gù ti ilẹ̀ Mágọ́gù máa gbéjà ko àwa èèyàn Jèhófà?