Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  August 2017

August 21-​27

Ìsíkíẹ́lì 35-38

August 21-​27
 • Orin 132 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Gọ́ọ̀gù Ti Ilẹ̀ Mágọ́gù Máa Tó Pa Run”: (10 min.)

  • Isk 38:2​—Ọ̀rọ̀ náà Gọ́ọ̀gù ti ilẹ̀ Mágọ́gù túmọ̀ sí àgbájọ àwọn orílẹ̀-èdè (w15 5/15 29-30)

  • Isk 38:​14-16​—Gọ́ọ̀gù ti ilẹ̀ Mágọ́gù máa gbéjà ko àwọn èèyàn Jèhófà (w12 9/15 5-6 ¶8-9)

  • Isk 38:​21-23​—Jèhófà máa ṣe ara rẹ̀ lógo, ó sì máa ya orúkọ rẹ̀ sí mímọ́ nígbà tó bá pa Gọ́ọ̀gù ti ilẹ̀ Mágọ́gù run (w14 11/15 27 ¶16)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Isk 36:​20, 21​—Kí ni ìdí pàtàkì tó fi yẹ ká máa hùwà rere? (w02 6/15 20 ¶12)

  • Isk 36:​33-36​—Báwo ni ọ̀rọ̀ yìí ṣe ní ìmúṣẹ lóde òní? (w88 9/15 24 ¶11)

  • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

  • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Isk 35:​1-15

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sm 37:29​—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni.

 • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jẹ 1:28; Ais 55:11​—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni.

 • Àsọyé: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w16.07 31-32​—Àkòrí: Kí Ni Ìtúmọ̀ Ọ̀rọ̀ Náà Pé A So Ọ̀pá Méjì Pa Pọ̀ Di Ọ̀kan?

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI