Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

 MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Àwọn Ànímọ́ Kristẹni Tó Yẹ Kó O Ní​—Ìgboyà

Àwọn Ànímọ́ Kristẹni Tó Yẹ Kó O Ní​—Ìgboyà

ÌDÍ TÓ FI ṢE PÀTÀKÌ:

BÓ O ṢE LÈ ṢE É:

  • Ṣàṣàrò lórí bí Jèhófà ṣe gba àwọn èèyàn rẹ̀ là.​—Ẹk 14:13

  • Bẹ Jèhófà pé kó fún ẹ ní ìgboyà. ​—Iṣe 4:​29, 31

  • Gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà.​—Sm 118:6

Àwọn nǹkan wo ló máa ń bà mí lẹ́rù lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù, báwo ni mo sì ṣe lè borí àwọn ìbẹ̀rù náà?

WO FÍDÍÒ NÁÀ, YẸRA FÚN OHUN TÓ LÈ BA ÌDÚRÓṢINṢIN RẸ JẸ́​—ÌBẸ̀RÙ ÈÈYÀN, LẸ́YÌN NÁÀ DÁHÙN ÀWỌN ÌBÉÈRÈ YÌÍ:

  • Kí nìdí tá a fi gbọ́dọ̀ ní ìgboyà lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù?

  • Ohun méjì tó yàtọ̀ síra wo ló wà nínú Òwe 29:25?

  • Kí nìdí tá a fi gbọ́dọ̀ máa fi ìgboyà ṣe ìfẹ́ Jèhófà nísinsìnyí?