Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  August 2017

August 14-​20

Ìsíkíẹ́lì 32-34

August 14-​20
 • Orin 114 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Iṣẹ́ Ńlá Ni Iṣẹ́ Olùṣọ́”: (10 min.)

  • Isk 33:7​—Jèhófà yan Ìsíkíẹ́lì láti jẹ́ olùṣọ́ (it-2 1172 ¶2)

  • Isk 33:​8, 9​—Bí olùṣọ́ náà bá kìlọ̀ fún àwọn èèyàn, kò ní jẹ̀bi ẹ̀jẹ̀ (w88 1/1 28 ¶13)

  • Isk 33:​11, 14-16​—Jèhófà máa dá ẹ̀mí àwọn tó bá gbọ́ ìkìlọ̀ náà sí (w12 3/15 15 ¶3)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Isk 33:​32, 33​—Kí nìdí tí a fi gbọ́dọ̀ tẹra mọ́ iṣẹ́ ìwàásù náà bí àwọn kan ò bá tiẹ̀ fẹ́ gbọ́ wa? (w91 3/15 17 ¶16-17)

  • Isk 34:23​—Báwo ni ohun tí ẹsẹ Ìwé Mímọ́ yìí sọ ṣe ní ìmúṣẹ? (w07 4/1 26 ¶3)

  • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

  • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Isk 32:​1-16

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI