Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò

Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò

JÍ!

Béèrè ìbéèrè: Báwo la ṣe lè máa lo àkókò wa bó ṣe tọ́?

Ka Bíbélì: Onw 4:6

Fi ìwé lọni: Ìwé ìròyìn Jí! yìí sọ bá a ṣe lè mọ àwọn ohun tó yẹ ká fi sí ipò àkọ́kọ́.

MÁA FI ÒTÍTỌ́ KỌ́NI

Béèrè ìbéèrè: Kí nìdí tá a fi wà láyé?

Ka Bíbélì: Sm 37:29

Òtítọ́: Ọlọ́run dá àwa èèyàn ká lè máa gbé títí láé lórí ilẹ̀ ayé.

ÌRÒYÌN AYỌ̀ LÁTỌ̀DỌ̀ ỌLỌ́RUN!

Béèrè ìbéèrè: Ibo lo rò pé a ti lè rí ìròyìn ayọ̀? [Jẹ́ kí onílé wo fídíò náà, Ṣé O Fẹ́ Gbọ́ Ìròyìn Ayọ̀?]

Ka Bíbélì: Ais 52:7

Fi ìwé lọni: Ìwé yìí sọ nípa “ìhìn rere ohun tí ó dára jù,” torí pé láti inú Bíbélì ni àwọn ọ̀rọ̀ inú rẹ̀ ti wá.

KỌ Ọ̀NÀ ÌGBỌ́RỌ̀KALẸ̀ RẸ

Wo àwọn ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ tá a fi ṣe àpẹẹrẹ yìí, kó o sì kọ ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ tìrẹ