Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | SÁÀMÙ 92-101

Bí Àwọn Àgbàlagbà Ṣe Lè Máa Sin Jèhófà Nìṣó

Bí Àwọn Àgbàlagbà Ṣe Lè Máa Sin Jèhófà Nìṣó

92:12

Igi ọ̀pẹ máa ń lo ju ọgọ́rùn-ún ọdún lọ láyé, síbẹ̀ á ṣì máa so èso

Àwọn àgbàlagbà máa ń so èso tẹ̀mí nígbà tí wọ́n bá ń . . .

92:13-15

  • gbàdúrà fún àwọn ẹlòmíì

  • kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì

  • lọ sáwọn ìpàdé ìjọ tí wọ́n sì ń kópa níbẹ̀

  • sọ àwọn ìrírí tí wọ́n ní fún àwọn ẹlòmíì

  • wàásù tọkàntọkàn