Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  August 2016

August 8 Sí 14

SÁÀMÙ 92-101

August 8 Sí 14
 • Orin 28 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Bí Àwọn Àgbàlagbà Ṣe Lè Máa Sin Jèhófà Nìṣó”: (10 min.)

  • Sm 92:12—Olódodo máa ń so èso tẹ̀mí (w07 9/15 ojú ìwé 32; w06 7/15 ojú ìwé 13 ìpínrọ̀ 2)

  • Sm 92:13, 14—Àwọn àgbàlagbà lè máa tẹ̀síwájú nípa tẹ̀mí láìka àìlera sí (w14 1/15 ojú ìwé 26 ìpínrọ̀ 17; w04 5/15 ojú ìwé 12 ìpínrọ̀ 9 àti 10)

  • Sm 92:15—Àwọn àgbàlagbà lè fún àwọn míì níṣìírí látinú ìrírí wọn (w04 5/15 ojú ìwé 12 sí 14 ìpínrọ̀ 13 sí 18)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Sm 99:6, 7—Kí nìdí tí Mósè, Áárónì àti Sámúẹ́lì fi jẹ́ àpẹẹrẹ àtàtà? (w15 7/15 ojú ìwé 8 ìpínrọ̀ 5)

  • Sm 101:2—Kí ló túmọ̀ sí láti ‘rìn ní ìwà títọ́ ọkàn’ nínú ilé wa? (w05 11/1 ojú ìwé 24 ìpínrọ̀ 14)

  • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

  • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sm 95:1–96:13

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

 • Orin 90

 • Ẹ̀yin Àgbàlagbà—Ẹ Ní Iṣẹ́ Ribiribi Láti Ṣe (Sm 92:12-15): (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò tá a pé àkọlé rẹ̀ ní Ẹ̀yin Àgbàlagbà—Ẹ Ní Iṣẹ́ Ribiribi Láti Ṣe. (Lọ sí tv.jw.org/yo, kó o sì wo abẹ́ WO FÍDÍÒ LÓRÍṢIRÍṢI > BÍBÉLÌ.) Lẹ́yìn náà, jẹ́ kí àwọn ará sọ àwọn ẹ̀kọ́ pàtàkì tí wọ́n rí kọ́. Gba àwọn àgbàlagbà níyànjú pé kí wọ́n máa ṣàjọpín ìrírí àti ọgbọ́n tí wọ́n ní pẹ̀lú àwọn ọ̀dọ́. Gba àwọn ọ̀dọ́ náà níyànjú pé kí wọ́n máa wá ìrànwọ́ lọ sọ́dọ̀ àwọn àgbàlagbà tí wọ́n bá fẹ́ ṣe àwọn ìpinnu pàtàkì.

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) ia orí 21 ìpínrọ̀ 13 sí 22, àtúnyẹ̀wò tó wà lójú ìwé 186

 • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

 • Orin 29 àti Àdúrà