Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | SÁÀMÙ 110-118

“Kí Ni Èmi Yóò San Pa Dà Fún Jèhófà?”

“Kí Ni Èmi Yóò San Pa Dà Fún Jèhófà?”

Onísáàmù náà mọ rírì Jèhófà gan-an ni, ìdí sì ni pé Jèhófà kó o yọ nínú “ìjàrá ikú.” (Sm 116:3) Láti fi hàn pé ó mọ rírì Jèhófà, ó pinnu pé òun máa mú gbogbo ìlérí òun ṣẹ̀ àti pé gbogbo ohun tí Jèhófà bá ní kí oun ṣe lòun máa ṣe.

Kí nìdí tó fi yẹ kí n mọ rírì Jèhófà lọ́sẹ̀ yìí?

Báwo ni mo ṣe lè fi hàn pé mo mọ rírì Jèhófà?