Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

August 29 Sí September 4

SÁÀMÙ 110-118

August 29 Sí September 4
 • Orin 61 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Kí Ni Èmi Yóò San Pa Dà Fún Jèhófà?”: (10 min.)

  • Sm 116:3, 4, 8—Jèhófà gba onísáàmù náà lọ́wọ́ ikú (w87 3/15 ojú ìwé 24 ìpínrọ̀ 5)

  • Sm 116:12—Onísáàmù náà fẹ́ fi ẹ̀mí ìmoore hàn sí Jèhófà (w09 7/15 ojú ìwé 29 ìpínrọ̀ 4 àti 5; w98 12/1 ojú ìwé 24 ìpínrọ̀ 3)

  • Sm 116:13, 14, 17, 18—Onísáàmù náà pinnu pé òun máa ṣe gbogbo ohun tó yẹ kí òun ṣe fún Jèhófà (w10 4/15 ojú ìwé 27, àpótí)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Sm 110:4—‘Ìbúra’ wo ni ẹsẹ yìí ń tọ́ka sí? (w14 10/15 ojú ìwé 11 ìpínrọ̀ 15 sí 17; w06 9/1 ojú ìwé 14 ìpínrọ̀ 1)

  • Sm 116:15—Kí nìdí tí kò fí yẹ kí ẹni tó ń sọ àsọyé ìsìnkú lo ọ̀rọ̀ inú ẹsẹ Bíbélì yìí fún ẹni tó kú náà? (w12 5/15 ojú ìwé 22 ìpínrọ̀ 2)

  • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

  • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sm 110:1–111:10

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) ll ojú ìwé 16—Sọ ohun tí wàá bá ẹni náà jíròrò nígbà tó o bá pa dà wá.

 • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) ll ojú ìwé 17—Sọ ohun tí wàá bá ẹni náà jíròrò nígbà tó o bá tún pa dà wá.

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh ojú ìwé 179 àti 180 ìpínrọ̀ 17 sí 19—Ran akẹ́kọ̀ọ́ náà lọ́wọ́ kó lè rí bó ṣe lè fi ohun tó kọ́ sílò.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

 • Orin 82

 • Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni”: (7 min.) Ìjíròrò.

 • Àkànṣe Ìwàásù Láti Pín Ìwé Ìròyìn Ilé Ìṣọ́ Lóṣù September”: (8 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo àkọ́kọ́ nínú àwọn fídíò ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ tá a lè lò ní oṣù September kẹ́ ẹ sì jíròrò àwọn kókó pàtàkì tó wà níbẹ̀. Ṣe iṣẹ́ yìí lọ́nà táá mú kí àwọn ará fi ìtara kọ́wọ́ ti àkànṣe ìwàásù yìí, sì gbà wọ́n níyànjú láti ṣe olùrànlọ́wọ́ aṣáájú-ọ̀nà.

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) ia ojú ìwé 23 ìpínrọ̀ 1 sí 14

 • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

 • Orin 144 àti Àdúrà

  Ìránnilétí: Jọ̀wọ́ jẹ́ kí àwọn ará kọ́kọ́ gbọ́ orin tuntun yìí lẹ́ẹ̀kan, lẹ́yìn náà, kí ẹ kọ ọ́.