Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  August 2016

August 22 Sí 28

SÁÀMÙ 106-109

August 22 Sí 28
 • Orin 2 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Ẹ Fi Ọpẹ́ Fún Jèhófà”: (10 min.)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Sm 109:8—Ṣé Ọlọ́run ló kádàrá Júdásì pé kó da Jésù kí àsọtẹ́lẹ̀ lè ṣẹ? (w00 12/15 ojú ìwé 24 ìpínrọ̀ 20; it-1-E ojú ìwé 857 àti 858)

  • Sm 109:31—Báwo ni Jèhófà ṣe “dúró ní ọwọ́ ọ̀tún òtòṣì”? (w06 9/1 ojú ìwé 14 ìpínrọ̀ 8)

  • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

  • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sm 106:1-22

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) ll ojú ìwé 6—Sọ ohun tí wàá bá ẹni náà jíròrò nígbà tó o bá pa dà wá.

 • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) ll ojú ìwé 7—Sọ ohun tí wàá bá ẹni náà jíròrò nígbà tó o bá tún pa dà wá.

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh ojú ìwé 178 sí 179 ìpínrọ̀ 14 sí 16—Ran akẹ́kọ̀ọ́ náà lọ́wọ́ kó lè rí bó ṣe lè fi ohun tó kọ́ sílò.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI