Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  August 2016

August 15 Sí 21

SÁÀMÙ 102-105

August 15 Sí 21
  • Orin 80 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) g16.4 ojú ìwé 10 àti 11—Sọ ohun tí wàá bá ẹni náà jíròrò nígbà tó o bá pa dà wá.

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) g16.4 ojú ìwé 10 àti 11—Sọ ohun tí wàá bá ẹni náà jíròrò nígbà tó o bá tún pa dà wá.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh ojú ìwé 164 sí 166 ìpínrọ̀ 3 àti 4—Ran akẹ́kọ̀ọ́ náà lọ́wọ́ kó lè rí bó ṣe lè fi ohun tó kọ́ sílò.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 91

  • Má Ṣe Gbàgbé Gbogbo Ohun Tí Jèhófà Ti Ṣe fún Ọ (Sm 103:1-5): (15 min.) Ìjíròrò. Kọ́kọ́ fi fídíò tó wà lórí ìkànnì jw.org/yo han àwọn ará. Àkọlé fídíò náà ni Ọ̀rọ̀ Ara Mi Sú Mi. (Wo abẹ́ NÍPA WA > OHUN TÁ À Ń ṢE.) Lẹ́yìn náà ẹ jíròrò àwọn ìbéèrè yìí: Kí nìdí tó fi yẹ ká máa yin Jèhófà? Nítorí inú rere Jèhófà, àwọn ìbùkún ọjọ́ iwájú wo là ń retí?

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) ia orí 22 ìpínrọ̀ 1 sí 13

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 131 àti Àdúrà