Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

August 1 Sí 7

SÁÀMÙ 87-91

August 1 Sí 7
 • Orin 49 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Má Ṣe Kúrò Ní Ibi Ìkọ̀kọ̀ Ẹni Gíga Jù Lọ”: (10 min.)

  • Sm 91:1, 2—“Ibi ìkọ̀kọ̀” Jèhófà ń pèsè ààbò fún wa nípa tẹ̀mí (w10 2/15 ojú ìwé 26 àti 27 ìpínrọ̀ 10 àti 11)

  • Sm 91:3—Bíi ti pẹyẹpẹyẹ, Sátánì fẹ́ dẹ pańpẹ́ mú wa (w07 10/1 ojú ìwé 26 sí 30 ìpínrọ̀ 1 sí 18)

  • Sm 91:9-14—Jèhófà ni ààbò wa (w10 1/15 ojú ìwé 10 àti 11 ìpínrọ̀ 13 àti 14; w01 11/15 ojú ìwé 19 àti 20 ìpínrọ̀ 13 sí 19)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Sm 89:34-37—Májẹ̀mú wo ni àwọn ẹsẹ Bíbélì yìí ń tọ́ka sí, báwo sì ni Jèhófà ṣe ṣàpẹẹrẹ bó ṣe jóòótọ́ tó? (w14 10/15 ojú ìwé 10 ìpínrọ̀ 14; w07 7/15 ojú ìwé 32 ìpínrọ̀ 3 àti 4)

  • Sm 90:10, 12—Báwo ni a ṣe ń ‘ka àwọn ọjọ́ wa lọ́nà tí a ó fi ní ọkàn-àyà ọgbọ́n’? (w06 7/15 ojú ìwé 13 ìpínrọ̀ 4; w01 11/15 ojú ìwé 13 ìpínrọ̀ 19)

  • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

  • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sm 90:1-17

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Múra Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Oṣù Yìí Sílẹ̀: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn fídíò ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀, kó o sì jíròrò àwọn kókó pàtàkì látinú àwọn fídíò náà. Gba àwọn ará níyànjú pé kí wọ́n kọ àwọn ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ wọn sílẹ̀.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI