Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁÀKÙ 1-2

“A Dárí Àwọn Ẹ̀ṣẹ̀ Rẹ Jì”

“A Dárí Àwọn Ẹ̀ṣẹ̀ Rẹ Jì”

2:5-12

Ẹ̀kọ́ wo ni a rí kọ́ nínú iṣẹ́ ìyanu yìí?

  • Ẹ̀ṣẹ̀ tá a jogún ló jẹ́ ká máa ṣàìsàn

  • Jésù ní agbára láti dárí ẹ̀ṣẹ̀ jini àti láti mú àwọn aláìsàn lára dá

  • Nínú Ìjọba Ọlọ́run, Jésù máa mú àìpé àti àìsàn kúrò títí láé

Báwo ni Máàkù 2:5-12 ṣe lè ràn mí lọ́wọ́ láti fara dà á tí mo bá ń ṣàìsàn?