WÒÓ
Ọ̀rọ̀
Àwòrán

Jèhófà sọ pé òun máa fi májẹ̀mú tuntun rọ́pò májẹ̀mú Òfin, èyí tó máa ṣàǹfààní títí láé.

MÁJẸ̀MÚ ÒFIN

 

MÁJẸ̀MÚ TUNTUN

Jèhófà àti orílẹ̀-èdè Ísírẹ́lì nípa tara

ÀWỌN TÓ KÀN

Jèhófà àti Ísírẹ́lì tẹ̀mí

Mósè

ALÁRINÀ

Jésù Kristi

Ẹran ni wọ́n fi ń rúbọ

OHUN TÓ FÌDÍ RẸ̀ MÚLẸ̀

Jésù fi ara rẹ̀ rúbọ

Wàláà òkúta

IBI TÁ A KỌ Ọ́ SÍ

Ọkàn àwọn èèyàn