Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

April 24-30

Jeremáyà 29-31

April 24-30
 • Orin 151 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Jèhófà Sọ Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Májẹ̀mú Tuntun”: (10 min.)

  • Jer 31:31—Ọgọ́rọ̀ọ̀rún ọdún ṣáájú ni Jèhófà ti sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa májẹ̀mú tuntun náà (it-1 524 ¶3-4)

  • Jer 31:32, 33—Májẹ̀mú tuntun náà yàtọ̀ sí májẹ̀mú Òfin (jr 173-174 ¶11-12)

  • Jer 31:34—Májẹ̀mú tuntun ló mú kí Jèhófà lè dárí ẹ̀ṣẹ̀ jì wá, tí kò sì ní rántí rẹ̀ mọ́ (jr 177 ¶18)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Jer 29:4, 7—Kí nìdí tí Jèhófà fi sọ fún àwọn Júù tó wà ní ìgbèkùn láti “máa wá àlàáfíà” Bábílónì, báwo la sì ṣe lè fi ìlànà yìí sílò? (w96 5/1 11 ¶5)

  • Jer 29:10—Báwo ni ẹsẹ Bíbélì yìí ṣe fi hàn pé àwọn àsọtẹ́lẹ̀ tó wà nínú Bíbélì péye? (g-E 6/12 14 ¶1-2)

  • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

  • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jer 31:31-40

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Mt 6:10—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni.

 • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ais 9:6, 7; Iṣi 16:14-16—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni.

 • Àsọyé: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w14 12/15 21—Àkòrí: Kí Ni Jeremáyà Ní Lọ́kàn Nígbà Tó Sọ Pé Rákélì Ń Sunkún Nítorí Àwọn Ọmọkùnrin Rẹ̀?

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI