• Orin 137 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Jẹ́ Onígboyà Bíi Jeremáyà”: (10 min.)

  • Jer 26:2-6—Jèhófà ní kí Jeremáyà kìlọ̀ fún àwọn èèyàn pé ìparun ń bọ̀ (w09 12/1 24 ¶6)

  • Jer 26:8, 9, 12, 13—Jeremáyà ò gbà káwọn ọ̀tá kó jìnnìjìnnì bá òun (jr 21 ¶13)

  • Jer 26:16, 24—Jèhófà dáàbò bo wolìí rẹ̀ tó jẹ́ onígboyà (w09 12/1 25 ¶1)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Jer 27:2, 3—Kí ló lè fà á tí àwọn ońṣẹ́ láti oríṣiríṣi orílẹ̀-èdè fi wá sí Jerúsálẹ́mù, kí sì nìdí tí Jeremáyà fi ṣe ọ̀pá àjàgà fún wọn? (jr 27 ¶21)

  • Jer 28:11—Báwo ni Jeremáyà ṣe lo làákàyè nígbà tí Hananáyà ta kò ó, kí nìyẹn sì kọ́ wa? (jr 187-188 ¶11-12)

  • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

  • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jer 27:12-22

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI