• Orin 52 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Ǹjẹ́ O Ní ‘Ọkàn-àyà Láti Mọ’ Jèhófà?”: (10 min.)

  • Jer 24:1-3—Jèhófà fi àwọn èèyàn wé èso ọ̀pọ̀tọ́ (w13 3/15 8 ¶2)

  • Jer 24:4-7—Àwọn èso ọ̀pọ̀tọ́ tó dára ṣàpẹẹrẹ àwọn tó fọkàn sí ọ̀rọ̀ Ọlọ́run tí wọ́n sì jẹ́ onígbọràn (w13 3/15 8 ¶4)

  • Jer 24:8-10—Èso ọ̀pọ̀tọ́ tí kò dára ṣàpẹẹrẹ àwọn ọlọ̀tẹ̀, tí ọkàn wọn ti yigbì, tí wọ́n sì jẹ́ aláìgbọràn (w13 3/15 8 ¶3)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Jer 22:30—Kí nìdí tí àṣẹ yìí kò fi fagi lé ẹ̀tọ́ tí Jésù ní láti gorí ìtẹ́ Dáfídì? (w07 3/15 10 ¶9)

  • Jer 23:33—Kí ni “ẹrù ìnira Jèhófà”? (w07 3/15 11 ¶1)

  • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

  • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jer 23:25-36

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI