Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  April 2016

April 25 sí May 1

JÓÒBÙ 33-37

April 25 sí May 1
 • Orin 50 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Ọ̀rẹ́ Tòótọ́ Máa Ń Sọ Ọ̀rọ̀ Tó Gbéni Ró”: (10 min.)

  • Job 33:1-5—Élíhù bọ̀wọ̀ fún Jóòbù (w95 2/15 ojú ìwé 29 ìpínrọ̀ 3 sí 5)

  • Job 33:6, 7—Élíhù jẹ́ onírẹ̀lẹ̀ àti onínúure (w95 2/15 ojú ìwé 29 ìpínrọ̀ 3 sí 5)

  • Job 33:24, 25—Élíhù fún Jóòbù níṣìírí kódà nígbà tó ń tọ́ Jóòbù sọ́nà (w11 4/1 ojú ìwé 23 ìpínrọ̀ 3; w09 4/15 ojú ìwé 4 ìpínrọ̀ 8)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Job 33:24, 25—Kí ló ṣeé ṣe kí “ìràpadà” tí Élíhù mẹ́nu kàn jẹ́? (w11 4/1 ojú ìwé 23 ìpínrọ̀ 3 sí 5)

  • Job 34:36—Báwo la ṣe máa dán Jóòbù wò tó, kí sì ni èyí kọ́ wa? (w94 11/15 ojú ìwé 17 ìpínrọ̀ 10)

  • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

  • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

 • Bíbélì Kíkà: Job 33:1-25 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Nígbà Àkọ́kọ́: Fi ìwé ìkésíni sí àpéjọ àgbègbè ti 2016 lọni. Lo ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ tó wà nínú ìwé yìí. (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

 • Ìpadàbẹ̀wò: fg ẹ̀kọ́ 12, ìpínrọ̀ 4 àti 5—Ṣe àṣefihàn bí a ṣe lè ṣe ìpadàbẹ̀wò ẹni tó gba ìwé ìkésíni sí àpéjọ àgbègbè invitation. Sọ ohun tí wàá bá ẹni náà jíròrò nígbà tó o bá tún pa dà wá. (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: jl ẹ̀kọ́ 11—Fún akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì rẹ níṣìírí láti lọ sí àpéjọ àgbègbè tó ń bọ̀. (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

 • Orin 124

 • Àwọn Ohun Tó Yẹ Ká Fi Sọ́kàn Nípa Àpéjọ Àgbègbè”: (8 min.) Àsọyé. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò tá a pe àkọlé rẹ̀ ní Àwọn Ohun Tó Yẹ Ká Fi Sọ́kàn Nípa Àpéjọ Àgbègbè. (Lọ sí home kó o wá wo abẹ́ WO FÍDÍÒ LÓRÍṢIRÍṢI > IṢẸ́ WA.) Gba àwọn ará níyànjú pé kí wọ́n ṣètò láti pésẹ̀ sí ọjọ́ mẹ́tẹ̀ẹ̀ta àpéjọ àgbègbè náà. Sọ ètò tí ìjọ yín ṣe fún pínpín ìwé ìkésíni sí àpéjọ àgbègbè.

 • Ohun tó ń fẹ́ àbójútó nínú ìjọ: (7 min.)

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: ia orí 14 ìpínrọ̀ 1 sí 13 (30 min.)

 • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

 • Orin 21 àti Àdúrà