Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé  |  April 2016

April 18 sí 24

JÓÒBÙ 28-32

April 18 sí 24
 • Orin 17 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Jóòbù Fi Àpẹẹrẹ Ìwà Títọ́ Lélẹ̀”: (10 min.)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Job 32:2—Ọ̀nà wo ni Jóòbù gbà “polongo ọkàn ara rẹ̀ ní olódodo dípò Ọlọ́run”? (w15 7/1 ojú ìwé 12 ìpínrọ̀ 2; it-1-E ojú ìwé 606 ìpínrọ̀ 5)

  • Job 32:8, 9—Kí ló mú kí Élíhù ronú pé òun lè sọ̀rọ̀ bó tilẹ̀ jẹ́ pé ó kéré sí àwọn tó ń bá sọ̀rọ̀? (w06 3/15 ojú ìwé 16 ìpínrọ̀ 1; it-2-E ojú ìwé 549 ìpínrọ̀ 6)

  • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

  • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

 • Bíbélì Kíkà: Job 30:24–31:14 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

 • Orin 115

 • Kẹ́kọ̀ọ́ Nínú Àpẹẹrẹ Ìwà Títọ́ Àwọn Ẹlòmíì (1Pe 5:9): (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò tá a pe àkọlé rẹ̀ ní Harold King: Ó Di Ìṣòtítọ́ Rẹ̀ Mú Lọ́gbà Ẹ̀wọ̀n. (Lọ sí home kó o wá wo abẹ́ WO FÍDÍÒ LÓRÍṢIRÍṢI > ÌFỌ̀RỌ̀WÁNILẸ́NUWÒ ÀTI ÌRÍRÍ.) Lẹ́yìn náà, jíròrò àwọn ìbéèrè yìí: Kí ni Arákùnrin King ṣe nígbà tó wà lẹ́wọ̀n tí ipò tẹ̀mí rẹ̀ kò fi jó rẹ̀yìn? Báwo ni kíkọ àwọn orin Ìjọba Ọlọ́run ṣe lè ràn wá lọ́wọ́ láti fara da ipò tí kò rọgbọ tá a bá wà? Báwo ni bí Arákùnrin King ṣe fi òótọ́ sìn Jèhófà ṣe fún ọ lókun?

 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: ia orí 13 ìpínrọ̀ 13 sí 25, àtúnyẹ̀wò tó wà lójú ìwé 114 (30 min.)

 • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀)

 • Orin 81 àti Àdúrà