Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

Sáàmù 150:1-6

150  Ẹ yin Jáà!+Ẹ yin Ọlọ́run nínú ibi mímọ́ rẹ̀.+Ẹ yìn ín nínú òfuurufú okun rẹ̀.+   Ẹ yìn ín fún àwọn iṣẹ́ rẹ̀ alágbára ńlá.+Ẹ yìn ín ní ìbámu pẹ̀lú ọ̀pọ̀ yanturu títóbi rẹ̀.+   Ẹ fi ìwo fífun yìn ín.+Ẹ fi ohun èlò ìkọrin olókùn tín-ín-rín àti háàpù yìn ín.+   Ẹ fi ìlù tanboríìnì+ àti ijó àjóyípo+ yìn ín.Ẹ fi àwọn ohun èlò ìkọrin olókùn tín-ín-rín+ àti fèrè ape+ yìn ín.   Ẹ fi àwọn aro tí ó ní ìró orin atunilára yìn ín.+Ẹ fi àwọn aro tí ń dún gooro yìn ín.+   Gbogbo ohun eléèémí—kí ó yin Jáà.+Ẹ yin Jáà!+

Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé