Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Bíbélì Orí Íńtánẹ́ẹ̀tì | ÌWÉ MÍMỌ́ NÍ ÌTUMỌ̀ AYÉ TUNTUN

Sáàmù 134:1-3

Orin Ìgòkè. 134  Ẹ fi ìbùkún fún Jèhófà,+Gbogbo ẹ̀yin ìránṣẹ́ Jèhófà,+Ẹ̀yin tí ẹ ń dúró nínú ilé Jèhófà ní òròòru.+   Ẹ gbé ọwọ́ yín sókè nínú ìjẹ́mímọ́,+Kí ẹ sì fi ìbùkún fún Jèhófà.+   Kí Jèhófà bù kún ọ láti Síónì wá,+Òun tí í ṣe Olùṣẹ̀dá ọ̀run àti ilẹ̀ ayé.+

Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé